November 13-19
JÓÒBÙ 15-17
Orin 90 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Má Ṣe Sọ̀rọ̀ Bí Élífásì Tó O Bá Ń Tu Àwọn Èèyàn Nínú”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Job 16:22—Ṣé ohun tí Jóòbù sọ níbí fi hàn pé kò gbà pé àjíǹde wà? (w06 3/15 14 ¶11)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 17:1-16 (th ẹ̀kọ́ 12)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Bíbélì—Job 26:7. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún un ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 1 ìbéèrè 6-10 (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 2 ¶1-7 àti ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ apá 1
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 118 àti Àdúrà