Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

November 20-26

JÓÒBÙ 18-19

November 20-26
  • Orin 44 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Job 19:​1, 2—Kí la rí kọ́ nínú bí Jóòbù ṣe fèsì nígbà tí “àwọn ọ̀rẹ́” rẹ̀ sọ àwọn ọ̀rọ̀ tó kó ẹ̀dùn ọkàn bá a? (w94 10/1 32)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 18:​1-21 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 90

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì bi wọ́n láwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni àwọn ọmọdé ṣe lè ran àwọn míì lọ́wọ́?

    Kí lo lè ṣe láti ran àwọn míì lọ́wọ́?

  • Ètò Tá A Ṣe Láti Tu Àwọn Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Nínú”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 2 ¶8-15

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 63 àti Àdúrà