November 6-12
JÓÒBÙ 13-14
Orin 151 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Tí Èèyàn Bá Kú, Ṣé Ó Tún Lè Wà Láàyè?”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Job 13:12—Kí nìdí tí Jóòbù fi sọ pé ọ̀rọ̀ àwọn olùtùnú èké rẹ̀ jọ “òwe tó dà bí eérú”? (it-1 191)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 13:1-28 (th ẹ̀kọ́ 12)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Bíbélì—2Ti 3:16, 17. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn àwọn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 1 ìbéèrè 1-5 (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Kí Kálukú Yín Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Gbóríyìn fáwọn ará fún bí wọ́n ṣe ń ya àwọn owó kan sọ́tọ̀ láti fi ti iṣẹ́ Jèhófà lẹ́yìn.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 1 ¶16-21
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 76 àti Àdúrà