Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 9-15

SÁÀMÙ 119:1-56

December 9-15

Orin 124 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Báwo Ni Ọ̀dọ́kùnrin Ṣe Lè Mú Ipa Ọ̀nà Rẹ̀ Mọ́?”

(10 min.)

Máa kíyè sára (Sm 119:9; w87 11/1 18 ¶10)

Rọ̀ mọ́ àwọn ìránnilétí Ọlọ́run (Sm 119:24, 31, 36; w06 6/15 25 ¶1)

Má ṣe máa wo ohun tí kò ní láárí (Sm 119:37; w10 4/15 20 ¶2)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn ìránnilétí wo ni mo ti gbọ́ táá jẹ́ kí n lè yẹra fún àwọn ohun tínú Ọlọ́run ò dùn sí?’

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 119—Ọ̀nà wo ni wọ́n gbà kọ sáàmù yìí, kí sì nìdí tí wọ́n fi kọ ọ́ bẹ́ẹ̀? (w05 4/15 10 ¶2)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Bá ẹnì kan tẹ́ ẹ pàdé lójú ọ̀nà sọ̀rọ̀ bẹ́ ẹ ṣe ń wàásù láti ilé dé ilé. (lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 4)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Nígbà kan tẹ́ ẹ jọ sọ̀rọ̀, ẹni náà sọ fún ẹ pé èèyàn òun kan kú láìpẹ́ yìí. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 3)

6. Àsọyé

(5 min.) ijwyp 83—Àkòrí: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ Ìdẹwò? (th ẹ̀kọ́ 20)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 40

7. Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December

8. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(5 min.)

9. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 19 ¶6-13

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 21 àti Àdúrà