October 10 sí 16
ÒWE 7-11
Orin 32 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọkàn-àyà Rẹ Yà Bàrá”: (10 min.)
Owe 7:6-12
—Àwọn tí ó jẹ́ aláìní ìrírí sábà máa ń kó sínú ewu nípa tẹ̀mí (w00 11/15 ojú ìwé 29 àti 30) Owe 7:13-23
—Bá a bá ṣi ìpinnu ṣe, ó lè yọrí sí wàhálà (w00 11/15 ojú ìwé 30 àti 31) Owe 7:4, 5, 24-27
—Ọgbọ́n àti òye máa dáàbò bò wá (w00 11/15 ojú ìwé 29 àti 31)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Owe 9:7-9
—Báwo ni ìdáhùn wa nígbà tí wọ́n bá wa wí ṣe ń sọ irú ẹni tá a jẹ́? (w01 5/15 ojú ìwé 29 àti 30) Owe 10:22
—Kí ni ìbùkún Jèhófà ní nínú fún wa lónìí? (w06 5/15 ojú ìwé 26 sí 30 ìpínrọ̀ 3 sí 16) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 8:22–9:6
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.5 tó wà lójú ìwé 2
—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.5
—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 176 ìpínrọ̀ 5 àti 6
—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ wá sí ìpàdé.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 83
Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fóònù (Owe 10:19): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ wo fídíò tá a pé àkọlé rẹ̀ ní Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fóònù. Lẹ́yìn náà, jíròrò àpilẹ̀kọ tó wà pẹ̀lú rẹ̀, tá a pè àkọlé rẹ̀ ní “Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?” Tẹnu mọ́ àwọn kókó tó wà lábẹ́ ìsọ̀rí náà “Béèyàn Ṣe Ń Fọ̀rọ̀ Ránṣẹ́.”
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 2 ìpínrọ̀ 13 sí 22
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 152 àti Àdúrà
Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.