October 17 sí 23
Òwe 12-16
Orin 69 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ọgbọ́n Dára Ju Wúrà Lọ”: (10 min.)
Owe 16:16, 17
—Ọlọ́gbọ́n èèyàn máa ń kẹ́kọ̀ọ́ ó sì máa ń fi Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sílò (w07 7/15 ojú ìwé 8) Owe 16:18, 19
—Ọlọ́gbọ́n èèyàn kì í gbéra ga tàbí jọ ara rẹ̀ lójú (w07 7/15 ojú ìwé 8 àti 9) Owe 16:20-24
—Ọlọ́gbọ́n èèyàn máa ń sọ̀rọ̀ rere tó lè ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ (w07 7/15 ojú ìwé 9 àti 10)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Owe 15:15
—Báwo la ṣe lè túbọ̀ láyọ̀ nígbèésí ayé? (g 01/14 ojú ìwé 16) Owe 16:4
—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà mú kí àwọn ẹni búburú ṣiṣẹ́ “fún ète rẹ̀”? (w07 5/15 ojú ìwé 18 àti 19) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 15:18–16:6
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 11:11-14
—Máa fi òtítọ́ kọ́ni. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 3:1-6; Ro 5:12
—Máa fi òtítọ́ kọ́ni. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 191 ìpínrọ̀ 18 àti 19
—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà wá sí ìpàdé.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 117
“Bá A Ṣe Lè Máa Dáhùn Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà
—Múra Ohun Tó O Máa Sọ ní Ìpàdé Sílẹ̀. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé mélòó kan wá sórí pèpéle kó o sì bi wọ́n pé: Ọ̀nà mẹ́rin wo lèèyàn lè gbà múra ìdáhùn sílẹ̀? Bí wọn kò bá tiẹ̀ pè wá, kí nìdí tá ò fi gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ìyẹn ba ayọ̀ wa jẹ́? Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 2 ìpínrọ̀ 23 sí 34
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 102 àti Àdúrà