October 24 sí 30
Òwe 17-21
Orin 76 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Wà Ní Àlàáfíà Pẹ̀lú Àwọn Ẹlòmíì”: (10 min.)
Owe 19:11
—Má Ṣe Fara Ya Tí Ẹnì Kan Bá Múnú Bí Ẹ (w14 12/1 ojú ìwé 12 àti 13) Owe 18:13, 17; 21:13
—Rí i pé o mọ gbogbo bọ́rọ̀ ṣe jẹ́ (w11 8/15 ojú ìwé 30 ìpínrọ̀ 11 sí 14) Owe 17:9
—Jẹ́ kí ìfẹ́ mú ẹ dárí ji ẹni tó ṣẹ̀ ẹ́ (w11 8/15 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 17)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Owe 17:5
—Kí nìdí tó fi yẹ ká fọgbọ́n yan eré ìnàjú tó yẹ ká máa wò? (w10 11/15 ojú ìwé 6 ìpínrọ̀ 17; w10 11/15 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 15) Owe 20:25
—Báwo ni ìlànà yìí ṣe kan ìfẹ́sọ́nà àti ìgbéyàwó? (w09 5/15 ojú ìwé 15 àti 16 ìpínrọ̀ 12 àti 13) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 18:14–19:10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ìwé ìkésíni sí àwọn ìpàdé ìjọ. (inv)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) inv
—Fi fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? hàn án láti kádìí ìjíròrò rẹ. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 57 ìpínrọ̀ 14 àti 15. Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè túbọ̀ máa múra lọ́nà tó bójú mu.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 77
Máa Wá Àlàáfíà Ko O Lè Rí Ìbùkún: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo Fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Máa Wá Àlàáfíà Ko O Lè Rí Ìbùkún. Lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí làwọn ohun tá a gbọ́dọ̀ yẹra fún tí wàhálà bá ṣẹlẹ̀? Ìbùkún wo la máa rí tá a bá ṣe ohun tí Òwe 17:9 àti Mátíù 5:23, 24 sọ?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 2 ìpínrọ̀ 35-40, àpótí Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?àti àwọn àtẹ “Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso” àti “A Múra Wọn Sílẹ̀ De Ìbí Ìjọba Náà”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 144 àti Àdúrà