October 1-7
JÒHÁNÙ 9-10
Orin 25 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jésù Ń Bójú Tó Àwọn Àgùntàn Rẹ̀”: (10 min.)
Jo 10:1-3, 11, 14—Jésù ni “olùṣọ́ àgùntàn àtàtà,” ó mọ àwọn àgùntàn rẹ̀ ní kọ̀ọ̀kan, ó sì máa ń pèsè ohun tí wọ́n nílò lọ́pọ̀ yanturu (“Ọgbà Àgùntàn” àwòrán àti fídíò lórí Jo 10:1, nwtsty; w11 5/15 7-8 ¶5)
Jo 10:4, 5—Àwọn àgùntàn Jésù dá ohùn rẹ̀ mọ̀, wọn ò mọ ohùn ẹlòmíì (cf 124-125 ¶17)
Jo 10:16—Àwọn àgùntàn Jésù wà ní ìṣọ̀kan (“mú wá” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 10:16, nwtsty)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Jo 9:38—Ọ̀nà wo ni ọkùnrin afọ́jú tó ń tọrọ bárà yẹn gbà wárí fún Jésù? (“wárí fún un” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 9:38, nwtsty)
Jo 10:22—Kí ni Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́? (“Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 10:22, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 9:1-17
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 14 ¶1-2
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 13 ¶16-26 àti àpótí Ìjọsìn Tòótọ́ Máa Ń Fúnni Láyọ̀ Tí Kò Lẹ́gbẹ́ [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ ka àpótí tàbí àfikún àlàyé]
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 3 àti Àdúrà