Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 13-14

“Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín”

“Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín”

13:5, 12-15

Jésù fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì rẹ̀, ó kọ́ wọn pé kí wọ́n jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ kí wọ́n sì máa ṣe àwọn iṣẹ́ tó rẹlẹ̀ fún àwọn arákùnrin wọn.

Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ . . .

  • tí wàhálà tàbí èdèkòyédè bá wáyé?

  • tí wọ́n bá fún mi nímọ̀ràn tàbí tí wọ́n bá tún ojú ìwòye mi ṣe?

  • tí wọ́n bá ní ká wá tún Gbọ̀ngàn Ìjọba wa ṣe?