Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

October 12-18

Ẹ́KÍSÓDÙ 33-34

October 12-18
  •  Orin 115 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Àwọn Ànímọ́ Jèhófà Tó Fani Mọ́ra”: (10 min.)

    • Ẹk 34:5​—Téèyàn bá mọ ohun tí orúkọ Ọlọ́run túmọ̀ sí, á mọ ohun tó fẹ́ ṣe, ohun tó ń ṣe àtàwọn ànímọ́ rẹ̀ (it-2 466-467)

    • Ẹk 34:6​—Àwọn ànímọ́ Jèhófà ń mú ká sún mọ́ ọn (w09 5/1 18 ¶3-5)

    • Ẹk 34:7​—Jèhófà máa ń dárí ji ẹlẹ́ṣẹ̀ tó bá ronú pìwà dà (w09 5/1 18 ¶6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 33:​11, 20​—Báwo ni Ọlọ́run ṣe bá Mósè sọ̀rọ̀ ní “ojúkojú”? (w04 3/15 27 ¶5)

    • Ẹk 34:​23, 24​—Kí nìdí táwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì fí nílò ìgbàgbọ́ kí wọ́n tó lè máa pàdé lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún? (w98 9/1 20 ¶5)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 33:​1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. E wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè pé: Báwo ni Jọkẹ́ ṣe ṣàlàyé ẹsẹ Bíbélì kó lè fa ẹ̀kọ́ ibẹ̀ yọ? Kí ni Jọkẹ́ ṣe kí onílé lè ronú jinlẹ̀?

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 16)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà fún onílé ní ìwé Bíbélì Kọ́ Wa, kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ ní orí 2. (th ẹ̀kọ́ 8)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI