Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

September 12 sí 18

SÁÀMÙ 120-134

September 12 sí 18
  • Orin 33 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Ọ̀dọ̀ Jèhófà Ni Ìrànlọ́wọ́ Mi Ti Wá”: (10 min.)

    • Sm 121:1, 2—Torí pé Jèhófà ló dá ohun gbogbo, èyí mú ká gbẹ́kẹ̀ lé e (w04 12/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 3)

    • Sm 121:3, 4—Jèhófà kì í fọ̀rọ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣeré rárá (w04 12/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 4)

    • Sm 121:5-8—Jèhófà ń dáàbò bo àwọn èèyàn rẹ̀ (w04 12/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 5 sí 7)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 123:2—Ẹ̀kọ́ wo ni àkàwé nípa “ojú àwọn ìránṣẹ́” kọ́ wa? (w06 9/1 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 4)

    • Sm 133:1-3—Kí ni ọ̀kan lára àwọn ẹ̀kọ́ tí a lè rí kọ́ nínú sáàmù yìí? (w06 9/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 3)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 127:1–129:8

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.5 tó wà lójú ìwé 2—Wàásù fún ẹnì kan tó ń bínú.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp16.5 —Pe ẹni náà wá sípàdé.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 8 ìpínrọ̀ 6—Ran akẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

  • Orin 114

  • Ọ̀pọ̀ Nǹkan Ni Jèhófà Ti Ṣe fún Mi: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò yìí. Ó wà lórí ìkànnì jw.org/yo.Ọ̀pọ̀ Nǹkan Ni Jèhófà Ti Ṣe fún Mi. (Lọ sí NÍPA WA > OHUN TÁ À Ń ṢE.) Ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni Jèhófà ṣe ran Crystal lọ́wọ́, kí sì lèyí mú kó ṣe? Kí ló máa ń ṣe nígbà tí èrò òdì bá ń kó ìbànújẹ́ bá a? Kí ni ìrírí Crystal kọ́ ẹ?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia Ìparí, ìpínrọ̀ 1 sí 13

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 119 àti Àdúrà