Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 120-134

“Ọ̀dọ̀ Jèhófà Ni Ìrànlọ́wọ́ Mi Ti Wá”

“Ọ̀dọ̀ Jèhófà Ni Ìrànlọ́wọ́ Mi Ti Wá”

Orin Ìgòkè làwọn èèyàn máa ń pe Sáàmù 120 sí 134. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà pé orin yìí làwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń fìdùnnú kọ nígbà tí wọ́n bá ń gba orí àwọn òkè ńlá Júdà lọ sí Jerúsálẹ́mù láti lọ ṣe àwọn àjọyọ̀ ọdọọdún.

Jèhófà ń dáàbò bò wá bí . . .

121:3-8

  • olùṣọ́ àgùntàn tó wà lójúfò

  • òjìji tó ń dáàbò boni lọ́wọ́ oòrùn

  • jagunjagun tó jẹ́ arógunmásàá