Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

September 19 sí 25

SÁÀMÙ 135-141

September 19 sí 25
  • Orin 59 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ọlọ́run Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-Tìyanu”: (10 min.)

    • Sm 139:14—Tá a bá ronú jinlẹ̀ nípa iṣẹ́ ọwọ́ Jèhófà, èyí á jẹ́ ká túbọ̀ mọrírì àwọn ohun tó ṣe (w07 6/15 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 1 sí 4)

    • Sm 139:15, 16—Àwọn sẹ́ẹ̀lì àtàwọn èròjà tó ń pinnu bí ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ṣe máa rí jẹ́ ká mọ bí ọgbọ́n àti agbára Jèhófà ṣe pọ̀ tó (w07 6/15 ojú ìwé 22 àti 23 ìpínrọ̀ 7 sí 11)

    • Sm 139:17, 18—Ọ̀nà tí Jèhófà gbà ṣẹ̀dá àwa èèyàn ṣàrà ọ̀tọ̀ gan-an; oríṣiríṣi èdè là ń sọ, bá a sì ṣe ń ronú yàtọ̀ síra (w07 6/15 ojú ìwé 23 ìpínrọ̀ 12 àti 13; w06 9/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 8)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 136:15—Òye wo ni ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí jẹ́ ká ní nípa ìwé Ẹ́kísódù? (it-1 ojú ìwé 783 ìpínrọ̀ 5)

    • Sm 141:5—Kí ni Dáfídì Ọba mọ̀? (w15 4/15 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 1)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 139:1-24

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.5 ojú ìwé 16

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.5 ojú ìwé 16—Pe ẹni náà wá sípàdé.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 8 ìpínrọ̀ 8—Ran akẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI