Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

September 26 sí October 2

SÁÀMÙ 142-150

September 26 sí October 2
  • Orin 134 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jèhófà Tóbi, Ó sì Yẹ fún Ìyìn Gidigidi”: (10 min.)

    • Sm 145:1-9—Títóbi Jèhófà kò ní ààlà (w04 1/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 3 àti 4; ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 7 àti 8; ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 20 àti 21; ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 2)

    • Sm 145:10-13—Àwọn tó jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà máa ń yìn ín (w04 1/15 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 3 sí 6)

    • Sm 145:14-16—Jèhófà máa ń ti àwọn tó jẹ́ adúróṣinṣin sí i lẹ́yìn, ó sì máa ń bójú tó wọn (w04 1/15 ojú ìwé 17 àti 18 ìpínrọ̀ 10 sí 14)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 143:8—Báwo ni Sáàmù 143:8 ṣe lè mú ká máa fi ògo fún Jèhófà ní gbogbo ọjọ́ ayé wa? (w10 1/15 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 1 àti 2)

    • Sm 150:6—Kí ni ẹsẹ tó gbẹ̀yìn nínú ìwé Sáàmù rọ̀ wá pé ká máa ṣe? (it-2 ojú ìwé 448)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 145:1-21

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Pe 5:7—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 37:9-11—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 9 ìpínrọ̀ 3—Ran akẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI