Arábìnrin kan ń wàásù lọ́nà àìjẹ́-bí-àṣà ní South Korea

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI September 2018

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ìfẹ́ tí Ọlọ́run ní sí àwa èèyàn.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ Tí Jésù Ṣe

Iṣẹ́ ìyanu àkọ́kọ́ tí Jésù ṣe jẹ́ ká mọ irú ẹni tó jẹ́.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jésù Wàásù fún Obìnrin Ará Samáríà Kan

Kí Jésù lè wàásù lọ́nà àìjẹ́-bí-àṣà, ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àpèjúwe kan tó dá lórí ohun tí obìnrin yẹn ń ṣe lójoojúmọ́.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bá A Ṣe Lè Sọ Ìjíròrò Lásán Di Ìwàásù

Bá a ṣe lè mú kí iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa sunwọ̀n sí i tá a bá fẹ́ bá àwọn tá à ò mọ̀ rí sọ̀rọ̀?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ní Èrò Tó Tọ́ Bó O Ṣe Ń Tẹ̀lé Jésù

Àwọn ọmọlẹ́yìn kan kọsẹ̀, wọn ò sì tẹ̀ lé Jésù mọ́, ìdí sì ni pé torí ohun tí wọ́n máa rí gbà ni wọ́n ṣe ń tẹ̀lé e.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Wọn Ò Fi Ohunkóhun Ṣòfò

Bí i Jésù, àwa náà lè fi ìmọrírì hàn fún àwọn ohun tí Jèhófà pèsè tí a kò bá fi wọ́n ṣòfò.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jésù Yin Baba Rẹ̀ Lógo

Ohun tó jẹ Jésù lógún jù ni bó ṣe máa ṣe iṣẹ́ tí Jèhófà gbé fún un yanjú.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ní Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀, Kó O Sì Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bí I Ti Jésù

Báwo la ṣe lè tẹ̀lé àpẹẹrẹ Jésù tí wọ́n bá fún wa láǹfààní iṣẹ́ ìsìn?