Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń wá a tọkàntọkàn?
Bíbélì: 1Pe 5:6, 7
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe nífẹ̀ẹ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa tó?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo ni Ọlọ́run ṣe nífẹ̀ẹ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa tó?
Bíbélì: Mt 10:29-31
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run mọ bí nǹkan ṣe ń rí lára wa?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run mọ bí nǹkan ṣe ń rí lára wa?
Bíbélì: Sm 139:1, 2, 4
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àǹfààní wo ló wà nínú bí Ọlọ́run ṣe ń bójú tó wa?