September 3-9
JÒHÁNÙ 1-2
Orin 13 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ Tí Jésù Ṣe”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù.]
Jo 2:1-3—Ohun tó lè dójú tini ṣẹlẹ̀ níbí àsè ìgbéyàwó kan (w15 6/15 4 ¶3)
Jo 2:4-11—Ohun tí Jésù ṣe mú kí ìgbàgbọ́ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ túbọ̀ lágbára (jy 41 ¶6)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Jo 1:1—Kí nìdí tá a fi gbà pé Jòhánù kò sọ pé ìkan náà ni “Ọ̀rọ̀ náà” àti Ọlọ́run Olódùmarè? (“ọ̀rọ̀ náà,” “pẹ̀lú,” “ọ̀rọ̀ náà sì jẹ́ ọlọ́run kan” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 1:1, nwtsty)
Jo 1:29—Kí nìdí tí Jòhánù Arinibọmi fi pe Jésù ní “Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run”? (“ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 1:29, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 1:1-18
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 41 ¶10-11
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 12 ¶9-14
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 121 àti Àdúrà