October 11-17
JÓṢÚÀ 10-11
Orin 149 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Joṣ 10:13—Kí nìdí tí kò fi pọn dandan ká mọ ohun tó wà nínú “ìwé Jáṣárì”? (w09 3/15 32 ¶5)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 10:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Jẹ́ Káwọn Míì Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Pèsè—Àwọn Ará.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 01 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 14 ¶21-25 àti àpótí 14A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 103 àti Àdúrà