ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Ìtàn Àwọn Ará Gíbíónì
Àwọn ará Gíbíónì fi hàn pé àwọn jẹ́ ọlọ́gbọ́n (Joṣ 9:3-6; it-1 930-931)
Àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì ò hùwà ọgbọ́n, torí wọn ò wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà (Joṣ 9:14, 15; w11 11/15 8 ¶14)
Onírẹ̀lẹ̀ làwọn ará Gíbíónì, wọ́n gbà láti máa ṣiṣẹ́ sin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (Joṣ 9:25-27; w04 10/15 18 ¶14)
Àwọn ará Gíbíónì gbà láti ṣiṣẹ́ tó rẹlẹ̀, torí pé wọ́n fẹ́ rí ojúure Jèhófà. Báwo là ṣe lè fi hàn pé a jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ bíi tiwọn?