September 20-26
JÓṢÚÀ 3-5
Orin 65 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Joṣ 5:14, 15, àlàyé ìsàlẹ̀.—Ta la gbà pé ó jẹ́ “olórí àwọn ọmọ ogun Jèhófà”? (w04 12/1 9 ¶1)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 3:1-13 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Pèsè—Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 01 ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ àti kókó 1-2 (th ẹ̀kọ́ 15)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 14 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 14
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 24 àti Àdúrà