ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Fara Wé Èlíṣà Tí Wọ́n Bá Ń Dá Ẹ Lẹ́kọ̀ọ́
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àwọn Ọba Kejì.]
Èlíṣà ń wo bí Èlíjà ṣe ṣiṣẹ́ ìyanu kan (2Ọb 2:8; w15 4/15 13 ¶15; wo àwòrán iwájú ìwé)
Èlíṣà nírẹ̀lẹ̀, bí Èlíjà ṣe kọ́ ọ gẹ́lẹ́ ló ṣe (2Ọb 2:13, 14; w15 4/15 13 ¶16)
Àwọn alàgbà ni Jèhófà fún ní ojúṣe láti máa dá àwọn míì lẹ́kọ̀ọ́ nínú ìjọ. (2Ti 2:2) Táwọn alàgbà bá fẹ́ dá ẹ lẹ́kọ̀ọ́, rí i pé o wà ní ìmúratán, o ṣeé fọkàn tán, ó sì nírẹ̀lẹ̀.