ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jẹ́ Onígboyà Bíi Ti Ásà
Ásà fìtara gbèjà ìjọsìn mímọ́ (1Ọb 15:11, 12; w12 8/15 8 ¶4)
Ásà nígboyà, ó sì ka ìjọsìn Jèhófà sí pàtàkì ju àjọṣe tó wà láàárín òun àtàwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ (1Ọb 15:13; w17.03 19 ¶7)
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Ásà ṣàṣìṣe, Jèhófà kà á sí olóòótọ́ torí ẹ̀mí rere tó ní (1Ọb 15:14, 23; it-1 184-185)
BI ARA RE PÉ: ‘Ṣé mo ní ìtara fún ìjọsìn mímọ́? Ṣé mi kì í bá àwọn tó bá fi Jèhófà sílẹ̀ kẹ́gbẹ́, kódà tí wọ́n bá jẹ́ mọ̀lẹ́bí mi?’—2Jo 9, 10.