ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI September–October 2023
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ran Àwọn Mí ì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Tí Ẹnì Kan Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ó Lo Àṣẹ Tó Ní Láti Ran Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lọ́wọ́
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tó Ń Ṣiṣẹ́ Kára fún Ire Àwọn Èèyàn Ọlọ́run
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Máa Lo Abala Ìbẹ̀rẹ̀ Orí Ìkànnì JW.ORG Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ṣọ́ra Fáwọn Ọ̀rọ̀ Tí Kì Í Ṣòótọ́
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Gbogbo Nǹkan Bá Tojú Sú Ẹ
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Jèhófà Ń Gba Àwọn Tí Àárẹ̀ Bá Ẹ̀mí Wọn Là
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì í Yẹ̀ Ń Dáàbò Bò Wá Lọ́wọ́ Irọ́ Sátánì
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ran Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Gbà Pé Ọlọ́run Wà
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ní Ọgbọ́n Ọlọ́run
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ