TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run?
Bíbélì: Ais 9:6, 7 tàbí Mt 6:9, 10
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:
ÌPADÀBẸ̀WÒ
Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?
Bíbélì: Sm 72:16 tàbí Mt 14:19, 20
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ìgbà wo ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣàkóso ayé?
WÀÁ RÍ SÁÀMÙ 72:16 NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: