Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Gbogbo Nǹkan Bá Tojú Sú Ẹ

Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Gbogbo Nǹkan Bá Tojú Sú Ẹ

Nígbà tí Jóòbù ń kojú àdánwò, ó fi ìgbésí ayé àwa èèyàn wé iṣẹ́ àṣekára tó pọn dandan (Job 7:1; w06 3/15 14 ¶10)

Ìnira mú kó sọ bí nǹkan ṣe rí lára ẹ̀ ní gbangba (Job 7:11)

Ó tiẹ̀ sọ pé ó sàn kí òun kú (Job 7:16; w20.12 16 ¶1)

Tí gbogbo nǹkan bá tojú sú ẹ, sọ gbogbo bó ṣe ń ṣe ẹ́ fún Jèhófà, kó o sì sọ bí nǹkan ṣe rí lára ẹ fún ọ̀rẹ́ rẹ kan tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú rẹ̀, ìyẹn máa jẹ́ kára tù ẹ́ díẹ̀.—g 4/12 20-21.