Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn

Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jóòbù.]

Sátánì sọ pé ìmọtara-ẹni-nìkan àtohun tí Jóòbù ń rí gbà lọ́wọ́ Ọlọ́run ló jẹ́ kó máa sìn ín (Job 1:​8-11; w18.02 6 ¶16-17)

Sátánì tún sọ pé ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ò nífẹ̀ẹ́ Jèhófà tọkàntọkàn (Job 2:​4, 5; w19.02 5 ¶10)

Jèhófà ti fún ẹnì kọ̀ọ̀kan wa láǹfààní láti fi hàn pé òpùrọ́ ni Sátánì. (Owe 27:11) Tá a bá ń fi Jèhófà sípò àkọ́kọ́ nígbèésí ayé wa nígbà dídùn àti nígbà kíkan, ṣe là ń fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ dénúdénú.