Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ran Àwọn Mí ì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà

Ran Àwọn Mí ì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà

Módékáì nígboyà, ó sì jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà (Ẹst 3:​2-4; it-2 431 ¶7)

Ó jẹ́ kí Ẹ́sítà mọ ohun tó máa ṣe kó lè ran àwọn èèyàn Ọlọ́run lọ́wọ́ (Ẹst 4:​7, 8; it-2 431 ¶9)

Ó gba Ẹ́sítà níyànjú pé kó nígboyà, kó sì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà (Ẹst 4:​12-14; ia 133 ¶22-23)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ìwà àti ọ̀rọ̀ ẹnu mi máa ń gbé àwọn tó wà nínú ìjọ ró, ṣé ó sì máa ń jẹ́ kó wù wọ́n láti túbọ̀ lo ara wọn lẹ́nu iṣẹ́ Jèhófà?’