Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀

Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀

Ẹ́sítà ṣe sùúrù kó tó sọ̀rọ̀ (Ẹst 7:2; ia 140 ¶15-16)

Ó fọgbọ́n sọ̀rọ̀, ó sì bọ̀wọ̀ fún ọba (Ẹst 7:3; ia 140 ¶17)

Ó sọ gbogbo bọ́rọ̀ ṣe rí láì fọ̀rọ̀ sábẹ́ ahọ́n sọ (Ẹst 7:4; ia 141 ¶18-19)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fara wé Ẹ́sítà tí mo bá ń bá àwọn mọ̀lẹ́bí mi sọ̀rọ̀?’