September 4-10
Ẹ́SÍTÀ 1-2
Orin 137 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Ẹst 2:5—Ẹ̀rí wo ló fi hàn pé ẹni gidi tó gbé láyé ni Módékáì tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀? (w22.11 31 ¶3-6)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹst 1:13-22 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ìjọba Ọlọ́run—Mt 6:9, 10. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 1)
Àsọyé: (5 min.) w20.11 13-14 ¶3-7—Àkòrí: Bí Jésù Àtàwọn Áńgẹ́lì Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́. (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Ìrísí: (5 min.) ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé: Kí nìdí tó fi lè ṣòro láti ní èrò tó tọ́ nípa ìrísí wa?
Báwo ni ìlànà tó wà ní 1 Pétérù 3:3, 4 ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti ní èrò tó tọ́ nípa ara wa?
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 56 àti àlàyé ìparí ìwé 6 àti 7
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 101 àti Àdúrà