Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà

Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sítà.]

Ẹ́sítà rẹwà gan-an (Ẹst 2:7)

Ẹ́sítà mọ̀wọ̀n ara ẹ̀ bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn ń yìn ín, wọ́n sì ń pọ́n ọn ju bó ṣe yẹ lọ (Ẹst 2:​9, 15; w17.01 25 ¶11; ia 130 ¶15)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ọ̀rọ̀ ẹnu mi àti ìwà mi fi hàn pé mo mọ̀wọ̀n ara mi àbí mo máa ń ka ara mi sí ju bó ṣe yẹ lọ?’—w17.01 25 ¶12.