October 21-27
SÁÀMÙ 100-102
Orin 37 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Fi Hàn Pé O Mọyì Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì Í Yẹ̀
(10 min.)
Jẹ́ kí ìfẹ́ tó o ní fún Jèhófà lágbára (Sm 100:5; w23.03 12 ¶18-19)
Yẹra fún ohunkóhun tó lè ba àjọṣe ìwọ àti Jèhófà jẹ́ (Sm 101:2, 3; w23.02 17 ¶10)
Sá fún àwọn tó ń sọ ohun tí ò dáa nípa Jèhófà àti ètò rẹ̀ (Sm 101:5; w11 7/15 16 ¶7-8)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣe àwọn nǹkan tí mò ń ṣe tàbí tí mò ń wò lórí ìkànnì àjọlò lè ba àjọṣe èmi àti Jèhófà jẹ́?’
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Sm 102:6—Kí nìdí tí onísáàmù náà fi fi ara ẹ̀ wé ẹyẹ òfú? (it-2 596)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Sm 102:1-28 (th ẹ̀kọ́ 12)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 3)
5. Pa Dà Lọ
(5 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 4)
6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́
(4 min.) Àṣefihàn. ijwbq 129—Àkòrí: Ṣé Wọ́n Ti Yí Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì Pa Dà? (th ẹ̀kọ́ 8)
Orin 137
7. ‘Mo Rọ̀ Mọ́ Ọ; O Dì Mí Mú’
(15 min.)
Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé:
Báwo ni Ánà ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn?
Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ̀?
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 17 ¶1-7