Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

January 8, 2001

Ǹjẹ́ ó Ṣeé Ṣe Kí Ìgbéyàwó Wa Má Forí Ṣánpọ́n?

Ṣé ọ̀nà kan ṣoṣo táa lè gbà yẹra fún ìkọ̀sílẹ̀ ni ká kàn máa jẹ́ tọkọtaya àmọ́ kó máà sífẹ̀ẹ́ láàárín wa? Kí ni tọkọtaya kan tí àjọṣe wọn kò gún régé mọ́ lè ṣe láti mú kí ìgbéyàwó wọn má forí ṣánpọ́n?

3 Híhá Sínú Ìgbéyàwó Aláìnífẹ̀ẹ́

4 Èé Ṣe Tí Ìfẹ́ Fi Ń Pòórá?

7 Ǹjẹ́ Ìrètí Ńbẹ?

8 Ó Ṣeé Ṣe Kí Ìgbéyàwó Yín Má Forí Ṣánpọ́n O!

15 Ibo Lo Ti Lè Rí Ẹ̀kọ́ Tó Dára Jù Lọ?

16 Ètò Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Tó Kárí Ayé

22 Ẹ̀kọ́ Tó Wúlò Títí Ayé

24 Yéé Sá fún Jíjẹ Oríṣiríṣi Ẹ̀fọ́!

28 Òdòdó Tulip Ni Ò Jẹ́ Kébi Pa Wọ́n Kú

32 N Kì Í Fẹ́ Gba Ohunkóhun Gbọ́, Síbẹ̀ Mo Ṣì Ń Wá A Káàkiri

Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn Ni Wọ́n Ra Ilé Iṣẹ́ Àkọ́kọ́ 25

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . 29

Báwo Ni Màá Ṣe Fara Dà Á Ní Báyìí Tí Dádì Ti Já Wa Sílẹ̀?