Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

July 8, 2001

Lílo Oògùn Olóró O Lè Jáwọ́ Ńbẹ̀!

Àwọn oògùn wo gan-an ni oògùn olóró? Kí ló fà á táwọn kan ò fi lè ṣàìlò ó? Ṣé ìṣòro yìí máa lójútùú tí á wà pẹ́ títí?

3 Oògùn—Ta Ló Ń Lò Ó?

6 Oògùn Olóró—Kí Ló Fà á Táwọn Èèyàn Fi Ń lò Ó?

9 Lílo Oògùn Olóró—O Lè Jáwọ́ Ńbẹ̀!

15 Ṣé Omi Ń tán Lọ Láyé Ni?

18 Ibo Ni Gbogbo Omi Ọ̀hún lọ?

22 A Ń fẹ́ Omi Ìyè

28 Kòkòrò Ìrẹ̀, Olórin Ìfẹ́

29 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . .

Ṣé Ọlọ́run Máa Dáhùn Àdúrà Mi?

32 Ó Ń pèsè Ìtùnú Nígbà Téèyàn Ẹni Bá Kú

Mo Gbé Àlàáfíà Lárugẹ Dípò Ogun 12

Kọ́ nípa ohun tó mú kí oníṣẹ́ ọnà kan fi iṣẹ́ oúnjẹ òòjọ́ kan tó ń mówó wọlé sílẹ̀.

Ojú Ìwòye Bíbélì 26

Ǹjẹ́ Ó Burú Kéèyàn Máa Ṣọ̀fọ̀?