Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

September 8, 2001

Ìrànwọ́ fún Àwọn Èwe Tó Sorí Kọ́

Ó dà bí ẹni pé àwọn èwe ń sorí kọ́ báyìí ju ti ìgbàkígbà rí lọ. Kí ló dé tí ọwọ́ àìsàn yìí fi ń tẹ̀ wọ́n tó bẹ́ẹ̀? Báwo la ṣe lè ràn wọ́n lọ́wọ́?

3 Àwọn Èwe Wà Nínú Ewu

5 Báa Ṣe Lè Dá Àwọn Àmì Ìsoríkọ́ Mọ̀

8 Ṣíṣàwárí Àwọn Nǹkan Tó Ń Fa Ìsoríkọ́

10 Bóo Ṣe Lè Ràn Wọ́n Lọ́wọ́

19 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . .

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Gbádùn Bíbélì Kíkà Sí I?

24 Àwọn Òbí Kọ̀ Mí Sílẹ̀—Ṣùgbọ́n Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Mi

28 Wíwo Ayé

30 Ojúṣe Bàbá Ò Ṣeé Fọwọ́ Rọ́ Sẹ́yìn

31 Ọ̀dọ́bìnrin Kan Tó Ní Ìrètí Amọ́kànyọ̀

32 Wáá Gbọ́ Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn Lọ́fẹ̀ẹ́

“Àwọn Wo Ló Ń Fi Òtítọ́ Kọ́ Gbogbo Orílẹ̀-Èdè?”

Ojú Tí Wọ́n Fi Ń Wo Àwọn Arúgbó Ń Yí Padà 15

Èrò tó wọ́pọ̀ nípa àwọn arúgbó ń yí padà. Kí làwọn àgbàlagbà lè ṣe kára wọn lè dá ṣámúṣámú kí wọ́n sì gbádùn ayé wọn?

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Fara Mọ́ Ṣíṣe Òwò Ẹrú? 22

Fífiniṣẹrú ti fa ìjìyà ńláǹlà fún àràádọ́ta ọ̀kẹ́ ènìyàn. Ǹjẹ́ Ọlọ́run fọwọ́ sí irú lílo ẹ̀dá ènìyàn nílòkulò bẹ́ẹ̀?