Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kejìlélọ́gọ́rin Ti Jí!

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kejìlélọ́gọ́rin Ti Jí!

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kejìlélọ́gọ́rin Ti Jí!

ÀJỌṢE Ẹ̀DÁ

Àwọn Arúgbó, 9/8

Bá A Ṣe Lè Dáàbò Bo Ìgbéyàwó, 1/8

Bíbá Ọmọ Wí, 11/8

Ìkórìíra Gbòde Kan, 8/8

Ìrànwọ́ fún Àwọn Obìnrin Tọ́kọ Wọn Ń Lù, 11/8

Máa Kàwé Sókè Ketekete fún Ọmọ Rẹ, 12/8

Ojúṣe Bàbá Ò Ṣeé Fọwọ́ Rọ́ Sẹ́yìn, 9/8

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

Àkúnya Omi ní Mòsáńbíìkì, 6/8

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Tó Kún fún Ìgbàgbọ́ Látinú Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Ọlọ́jọ́ Pípẹ́ Kan (orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà), 12/8

Àwọn Olùyọ̀ǹda Ara Ẹni, 8/8

Ẹ̀kọ́ Tó Wúlò fún Ìgbésí Ayé, 1/8

Ìsìn Tí Ilẹ̀ Soviet Dojú Àtakò Kọ, 5/8

Mo Ń Fara Da Ìbànújẹ́ Ńláǹlà Kan (J. Giarrano), 8/8

Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn Ni Wọ́n Ra Ilé Iṣẹ́ Àkọ́kọ́ (àwọn ọ́fíìsì ẹ̀ka), 1/8

ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN

Adìyẹ, 10/8

Ìgbádùn Tó Wà Nínú Wíwo Ẹyẹ, 3/8

Kòkòrò Ìrẹ̀—Olórin Ìfẹ́, 7/8

Òdòdó Tulip Ni Ò Jẹ́ Kébi Pa Wọ́n Kú, 1/8

ÀWỌN OHUN TÓ Ń ṢẸLẸ̀ NÍNÚ AYÉ

Àwọn Ìlú Ńlá Wà Nínú Ìṣòro, 4/8

Àwọn Ohun Èèlò Tó Ń Pani (àwọn ohun ìjà kéékèèké), 4/8

Àwọn Olùyọ̀ǹda Ara Ẹni, 8/8

Fífarada Kòókòó Jàn-ánjàn-án, 2/8

Ìkórìíra Gbòde Kan, 8/8

Ìṣòro Dé Bá Àwọn Ọgbà Ẹ̀wọ̀n, 5/8

Lílo Oògùn Olóró, 7/8

Ǹjẹ́ A Lè Ṣọ̀gbìn Oúnjẹ Tó Máa Pọ̀ Tó? 10/8

Ǹjẹ́ A Máa Ní Ànító Omi? 7/8

Wọ́n Lè Jí Ohun Ìdánimọ̀ Rẹ Lọ, 4/8

‘Wọn Yóò Fi Idà Wọn Rọ Abẹ Ohun Ìtúlẹ̀’—Nígbà Wo? 3/8

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ

Àdúrà, 7/8, 8/8

Àwọn Bàbá Tí Wọ́n Sá Kúrò Nílé, 1/8

Àwọn Òbí Àgbà, 5/8, 6/8

Àwọn Oníbìínú Èèyàn, 12/8

Báwo Ni Màá Ṣe Sọ fún Un Pé Mi Ò Ṣe? 4/8

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dẹ́kun Dídààmú? 10/8

Dídájọ́ Àjọròde, 2/8

Gbígbádùn Bíbélì Kíkà, 9/8

Gbígbẹ̀san, 11/8

Yíyọ́ Jáde Nílé, 3/8

ÈTÒ ỌRỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́

‘Òfo ni Àyẹ̀wò Ọ̀hún Já Sí’ (ètò ọrọ̀ ajé kárí ayé), 11/8

ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN

Àrùn Oríkèé-Ara-Ríro, 12/8

Àwọn Èwe Tó Sorí Kọ́, 9/8

Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ (nínú ọkọ̀), 10/8

Ìlera fún Gbogbo Èèyàn, 6/8

Ìṣirò Nípa Àrùn Éèdì, 3/8

Ìṣòro Àìsàn, 2/8

Ìwàláàyè Ṣe Pàtàkì (ìfọwọ́-ara-ẹni-gbẹ̀mí-ara-ẹni), 11/8

Yéé Sá fún Jíjẹ Oríṣiríṣi Ẹ̀fọ́! 1/8

ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN

A Rìnrìn Àjò Lọ sí Ọgbà Ẹranko ní Gánà, 6/8

Ènìyàn Ti Fìyà Jẹ Ẹlẹgbẹ́ Rẹ̀ (Àwọn Àmẹ́ríńdíà), 11/8

Ìlú Tí Àṣà Ìlà Oòrùn àti Ìwọ̀ Oòrùn Ayé Ti Wọnú Ara Wọn (Gúúsù Áfíríkà), 10/8

Sísọ Aṣálẹ̀ Di Ilẹ̀ Eléso (Íńdíà), 4/8

ÌSÌN

Àwọn Kàtídírà, 12/8

Bíbélì—Ṣó Yẹ Ká Gba Àwọn Ìtàn Inú Rẹ̀ Gbọ́? 3/8

Ilẹ̀ Soviet Gbógun Ti Ìsìn, 5/8

Orúkọ Ọlọ́run Dá Awuyewuye Sílẹ̀, 12/8

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Àwọn Òbí Kọ̀ Mí Sílẹ̀—Ṣùgbọ́n Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Mi (B. Finn), 9/8

Bí Mo Tilẹ̀ Dití tí Mo Tún Fọ́jú, Mo Rí Ààbò (J. Adams), 6/8

Màmá Àtàwọn Ọmọbìnrin Rẹ̀ Mẹ́wàá (E. Lozano), 11/8

Mo Gbé Àlàáfíà Lárugẹ Dípò Ogun (D. Horle), 7/8

Ogun Ò Dáṣẹ́ Ìwàásù Wa Dúró (L. Barlaan), 3/8

Orúkọ Ọlọ́run Ló Yí Ìgbésí Ayé Mi Padà! (S. Tsosie), 10/8

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Aṣòdì sí Kristi, 8/8

Àwọn Ìpàdé Ìjọ, 3/8

Báwo Ni Ọlọ́run Ṣe Ń Mú Nǹkan Mọ́ra Tó? 10/8

Lílò Tí Ọlọ́run Ń Lo Agbára Rẹ̀ Láti Pa Àwọn Ẹni Ibi Run, 11/8

Ǹjẹ́ Ó Burú Kéèyàn Máa Ṣọ̀fọ̀? 7/8

Òwò Ẹrú, 9/8

Ṣé Ìsọfúnni Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Àlá Jẹ́? 4/8

Ṣé Oríṣiríṣi Ọ̀nà Tó Lọ Sọ́dọ̀ Ọlọ́run Ni Àwọn Ìsìn Jẹ́? 6/8

Ṣé Ó Yẹ Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí? 2/8

Ṣé Ọlọ́run Ẹ̀yà Júù Ni Jèhófà? 5/8

Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN

Ìpakúpa Rẹpẹtẹ Tó Wáyé Nígbà Ìjọba Násì—Ṣé Ó Ṣì Tún Lè Ṣẹlẹ̀? 5/8

Ǹjẹ́ O Mọ̀? 2/8, 4/8, 6/8, 10/8, 12/8