Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

February 8, 2003

Àwọn Ọmọdé Tó Ń ṣiṣẹ́ Aṣẹ́wó—Ọ̀ràn Ìbànújẹ́ Tó Dóde

Ọ̀kẹ́ àìmọye àwọn ọmọdé ló ń ṣiṣẹ́ aṣẹ́wó káàkiri àgbáyé. Ìgbà wo ni ìṣòro bíburú jáì yìí máa dópin?

3 “Ìwà Ìbàjẹ́ Tó Burú Jáì”

5 Kí Ló Dé Tí Ìṣòro Yìí Fi Ń peléke Sí I?

8 Fífi Àwọn Ọmọdé Ṣèfà Jẹ Máa Dópin Láìpẹ́!

11 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

14 Máa Lóye Ọ̀ràn Dáadáa Kó o Tó Gbà á Gbọ́

15 Ǹjẹ́ Àwọn Kan Ń Ṣọ́ Ọ?

17 Kò Sí Àṣírí Mọ́

21 Ojú Tó Yẹ Ká Máa Fi Wo Ọ̀ràn Àṣírí

28 Wíwo Ayé

30 Rí I Pé Ò Ń Sùn Dáadáa!

31 Ẹ̀rín Músẹ́ Dáa fún Ara

32 Atẹ́gùn Ló Gbé E Wá

Ǹjẹ́ Ẹ̀ṣẹ̀ Kan Wà Tí Kò Ní Ìdáríjì? 12

Ǹjẹ́ Bíbélì sọ pé ẹ̀ṣẹ̀ kan wà tí Ọlọ́run kì í dárí rẹ̀ jini?

Kí Ló Burú Nínú Jíjíwèé Wò? 25

Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ máa ń jíwèé wò níléèwé. Kí nìdí tí wọ́n fi ń ṣe bẹ́ẹ̀? Ìdí wo ló sì fi yẹ kó o yẹra fún àṣà yìí?

[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]

Ẹ̀YÌN ÌWÉ: © Fọ́tò Jan Banning/Panos, 1997

© Fọ́tò Shehzad Noorani/Panos