Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 08, 2003
Àwọn Ohun Arùfẹ́-ìṣekúṣe-sókè—Ǹjẹ́ Wọ́n Lè Pani Lára Tàbí Wọn Kò Lè Pani Lára?
Àwọn kan ń bẹnu àtẹ́ lu àwọn ohun arùfẹ́-ìṣekúṣe-sókè pé wọ́n lè pani lára. Àwọn mìíràn sì sọ pé ọ̀rọ̀ ò rí bẹ́ẹ̀, wọ́n ní àmì pàtàkì tó ń fi hàn pé àwọn èèyàn tó jẹ́ ọlọ́pọlọ pípé, tí kì í sì í fọ̀rọ̀ bò ló wà láwùjọ wa. Kí ló mú kí àwọn ohun arùfẹ́-ìṣekúṣe-sókè gbilẹ̀ tó bẹ́ẹ̀? Ṣé lóòótọ́ ni wọ́n léwu?
3 Èrò Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Tí Àwọn Èèyàn Ní Nípa Àwọn Ohun Arùfẹ́-ìṣekúṣe-sókè
4 Kí Nìdí Tí Àwọn Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè Fi Gbilẹ̀ Tó Bẹ́ẹ̀?
6 Ìpalára Tí Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè Ń Ṣe
Kí Ló Máa Ń Mú Mi Ronú Pé Kò Yẹ Kí N Ṣe Àṣìṣe Kankan?
21 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
22 Ohun Kan Tí Ìjì Kò Lè Gbé Lọ
28 Wíwo Ayé
31 Wọ́n Ń Ṣe Àwọn Aráàlú Láǹfààní
32 Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ẹni Ọ̀wọ́n Kan
Ǹjẹ́ Ó Tọ́ Láti Kórìíra Ẹ̀yà Mìíràn? 14
Kíkórìíra ẹ̀yà mìíràn ti fa àwọn ogun tó ti fẹ̀mí àwọn èèyàn ṣòfò lọ́pọ̀lọpọ̀, kódà láwọn ọdún lọ́ọ́lọ́ọ́ yìí pàápàá. Ǹjẹ́ Bíbélì lọ́nà èyíkéyìí tiẹ̀ fara mọ́ irú ìwà kèéta bẹ́ẹ̀?
Ìdí Táwọn Èèyàn Fi Ka Erékùṣù Tahiti sí Párádísè Tí Wọ́n Ń Wá Kiri 16
Erékùṣù Pàsífíìkì yìí ní ọ̀pọ̀ àwọn nǹkan àdánidá tó mú kó lẹ́wà gan-an. Àmọ́, ǹjẹ́ lóòótọ́lóòótọ́ ló jẹ́ Párádísè tí aráyé ń yán hànhàn fún láti gbé?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Tahiti: Fọ́tò nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda Tahiti Tourisme