Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹrìnlélọ́gọ́rin Ti jí!
Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹrìnlélọ́gọ́rin Ti jí!
ÀJỌṢE Ẹ̀DÁ
Fífòòró Ẹni, 9/8
Ìgbà Èwe, 5/8
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìgbéyàwó Jẹ́ Aláyọ̀, 10/8
Oògùn Olóró Nínú Ìdílé, 4/8
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Àpéjọ “Ẹ Fi Ògo fún Ọlọ́run,” 9/8
Aráàlú Ṣèbẹ̀wò Tó Mórí Wọn Wú (Jámánì), 3/8
Àròkọ Wú Wọn Lórí Gan-an (akẹ́kọ̀ọ́), 9/8
Fífi Ìfẹ́ Hàn Nígbà Ìṣòro (Nàìjíríà), 3/8
Iléeṣẹ́ Kẹ́míkà Bú Gbàù (ilẹ̀ Faransé), 4/8
Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Ilẹ̀ Amẹ́ríkà Dá Ẹ̀tọ́ Òmìnira Ọ̀rọ̀ Sísọ Padà, 1/8
Kò Retí Pé Òun Á Ṣàṣeyọrí Tó Tóyẹn (Jámánì), 5/8
Lẹ́yìn Tí Ìbúgbàù Náà Wáyé (Ecuador), 10/8
Ohun Kan Tí Ìjì Kò Lè Gbé Lọ (iṣẹ́ ìrànwọ́), 8/8
Omíyalé ní Àgbègbè Caucasus, 11/8
Ó Yàn Láti Ṣègbọràn sí Ọlọ́run (A. Gargallo, Sípéènì), 3/8
‘Ṣègbọràn sí Ọlọ́run Dípò Àwọn Ènìyàn’ (iṣẹ́ ọnà), 1/8
Wọ́n Ń Ṣe Àwọn Aráàlú Láǹfààní (Gbọ̀ngàn Ìjọba), 8/8
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN
Àwọn Ọmọ Ogun Tó Ń Yan Lọ (ìjàlọ), 6/8
Ẹ̀pà, 5/8
Ohun Àgbàyanu Ni Ṣíṣílọ Wọn (ẹranko wildebeest), 3/8
Ojú Ẹyẹ Idì, 1/8
Oko Ọ̀gẹ̀dẹ̀, 4/8
Ọ̀kan Lára Àwọn Èso Tó Wúlò Jù Lọ (àgbọn), 4/8
Pípèsè Oúnjẹ Látinú Oko Rẹ, 12/8
ÀWỌN OHUN TÓ Ń ṢẸLẸ̀ NÍNÚ AYÉ
Àìjẹunrekánú, 3/8
Àwọn Ọmọdé Tó Ń Ṣiṣẹ́ Aṣẹ́wó, 2/8
Epo Rọ̀bì—Ṣé Wọ́n Lè Wà Á Gbẹ? 11/8
Fífòòró Ẹni, 9/8
Ìlànà Rere, 6/8
Ìṣòro Tó Wà Nídìí Iṣẹ́ Àgbẹ̀, 10/8
Ìwà Ìkà Bíburú Jáì, 7/8
Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè, 8/8
Oògùn Olóró Nínú Ìdílé, 4/8
Ọ̀ràn Àṣírí, 2/8
Ṣe Owó Orí Tí Ò Ń San Ti Pọ̀ Jù? 12/8
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Làwọn Èèyàn Ṣe Lè Máa Fi Ọ̀wọ̀ Tèmi Wọ̀ Mí? 11/8
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Ẹ̀mí Ṣohun-Tẹ́gbẹ́-Ń-Ṣe? 1/8
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Fífi Ẹ̀gbọ́n Mi Ṣe Àwòkọ́ṣe Nínú Gbogbo Nǹkan? 12/8
Fídíò Orin, 3/8, 4/8
Jíjíwèé Wò, 2/8
Nígbà Tí Àjálù Bá Wáyé, 7/8
Ọmọ Àgbàtọ́, 5/8, 6/8
Ṣé Kí N Fín Ara? 10/8
Ṣíṣàì Fẹ́ Ṣe Àṣìṣe Kankan? 8/8, 9/8
ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN
Àìjẹunrekánú, 3/8
Àrùn Àtọ̀gbẹ, 5/8
Àrùn Tí Kòkòrò Ń Gbé Kiri, 6/8
Àwọn Nǹkan Tó Lè Nípa Lórí Ìlera, 9/8
Bí Àìsàn Ibà Bá Ń Ṣe Ọmọ Rẹ, 12/8
Bó O Ṣe Lè Túbọ̀ Dáàbò Bo Oyún Rẹ, 1/8
Igi Tẹ́ẹ́rẹ́ Tó Ń Fọ Eyín Mọ́, 9/8
Omi, 6/8
Oorun, 4/8
Ọ̀nà Mẹ́fà Tí O Lè Gbà Dáàbò Bo Ìlera Rẹ, 10/8
Ọṣẹ “Abẹ́rẹ́ Àjẹsára” Tó O Lè Gún Fúnra Rẹ, 12/8
Rí I Pé Ò Ń Sùn Dáadáa! 2/8
Sísanra Jọ̀kọ̀tọ̀—Ǹjẹ́ Kò Ti Ń Di Àjàkálẹ̀ Àrùn Tó Kárí Ayé Báyìí? 12/8
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN
Ìdí Táwọn Èèyàn Fi Ka Erékùṣù Tahiti sí Párádísè Tí Wọ́n Ń Wá Kiri, 8/8
“Ìlù Onígba-Ohùn” (Áfíríkà), 8/8
Ìlú Tí Wọ́n Ti Ń Wa Góòlù Dúdú (Brazil), 3/8
Omíyalé ní Àgbègbè Caucasus, 11/8
Òwe Ẹ̀yà Akan (Gánà), 7/8
Piñata (Mẹ́síkò), 10/8
Ṣíṣèbẹ̀wò sí Jerúsálẹ́mù ní Ìlú Quebec, 9/8
ÌSÌN
Àṣà Tí Kò Pa Rẹ́ (Bàbá Kérésìmesì), 5/8
Ìwé Tó Ń Gbógun Ti Ìwé Mìíràn (Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì), 9/8
“Jèhófà Ni Olùtùnú Mi” (ọba ilẹ̀ Sweden), 7/8
Orúkọ Jèhófà ní Erékùṣù Pàsífíìkì, 11/8
“Ọdún Bíbélì,” 10/8
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Àdánwò Ìgbàgbọ́ ní Slovakia (J. Bali), 1/8
Bí A Ṣe Pa Òùngbẹ Tẹ̀mí Tó Ń Gbẹ Mí (L Moussanett), 7/8
Mo Borí Ẹ̀mí Ìkórìíra (J. Gomez), 1/8
Mo Fara Mọ́ Ohun Tí Ọlọ́run Sọ Nípa Ẹ̀jẹ̀ (Y. Aizawa), 12/8
Ohun Tó Mú Kí Ìgbésí Ayé Mi Nítumọ̀ (E. Pandachuk), 11/8
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Báwo Lo Ṣe Lè Yẹra fún Èrò Tí Kò Tọ́? 12/8
Ẹ̀sìn Rẹ àti Tàwọn Ìbátan Rẹ Ò Dọ́gba, 11/8
Ẹ̀ṣẹ̀ Tí Kò Ní Ìdáríjì, 2/8
Gbígbé Ìgbésí Ayé Tó Yàtọ̀ Sí Ti Ẹ̀dá, 10/8
Kí Ni Ìfẹ́ Ọrọ̀ Àlùmọ́ọ́nì? 4/8
Ǹjẹ́ Ìṣọ̀kan Kristẹni Ń Béèrè Pé Kí Ìpinnu Àwọn Kristẹni Dọ́gba? 5/8
Ǹjẹ́ Ó Pọn Dandan Kí Àwọn Kristẹni Jẹ́ Tálákà? 1/8
Ǹjẹ́ Ó Tọ́ Láti Kórìíra Ẹ̀yà Mìíràn? 8/8
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Jẹ́ Kí Wọ́n Mú Àwọn Níyè? 7/8
Òmìnira Láti Ṣèpinnu? 3/8
Ṣé Jíjẹ́ Ọlọ́rọ̀ Ló Ń Fi Hàn Pé A Ní Ìbùkún Ọlọ́run? 9/8
Yíyẹra fún Sísọ Ọ̀rọ̀ Tó Máa Ń Dunni, 6/8
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
Aṣọ Tó Bá Dóde, 9/8
Ẹ̀rín Músẹ́, 2/8
Máa Lóye Ọ̀ràn Dáadáa Kó O Tó Gbà Á Gbọ́ (Íńtánẹ́ẹ̀tì), 2/8
Ǹjẹ́ O Mọ̀? 2/8, 6/8, 7/8, 8/8, 10/8, 12/8
Òpin Ọ̀sẹ̀, 7/8