Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

January 8, 2005

Ṣé Bíba Ilé Ayé Jẹ́ Á Dópin?

Àwọn èèyàn ti fẹ́rẹ̀ẹ́ ba àwọn àlùmọ́ọ́nì inú ayé jẹ́ tán. Ta là bá ké sí kó bá wa dáwọ́ ẹ̀ dúró?

3 Wọ́n Ti Ba Ayé Yìí Jẹ́ Jìnnà

4 Àwọn Àlùmọ́ọ́nì Ilẹ̀ Ti Fẹ́rẹ̀ẹ́ Run Tán

10 Bíba Ilé Ayé Jẹ́ Máa Dópin!

15 Wọ̀n Ń Ṣàníyàn Jù Nítorí Ẹwà

16 Ewu Tó Wà Nínú Kéèyàn Fẹ́ Lẹ́wà Ní Gbogbo Ọ̀nà

20 Irú Ẹwà Tó Ṣe Pàtàkì Jù

24 Nairobi “Odò Omi Tútù”

28 Iléeṣẹ́ Gbẹ̀mígbẹ̀mí

29 A Ṣèbẹ̀wò Mánigbàgbé Sínú Ihò Ngorongoro

Bó Bá Lóun Ò Lè Fẹ́ Mi Ńkọ́? 12

Kí ni ọ̀dọ́mọbìnrin kan lè ṣe bí ọ̀dọ́mọkùnrin kan tó wù ú láti fẹ́ ò bá gbà láti fẹ́ ẹ?

Ṣé Ọ̀dẹ̀ Lẹni Tó Bá Jẹ́ Èèyàn Pẹ̀lẹ́? 22

Ọ̀pọ̀ èèyàn á dáhùn pé bẹ́ẹ̀ ni, àmọ́ Bíbélì fi hàn pé ọ̀rọ̀ ò rí bẹ́ẹ̀.

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]

ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: NASA JSC