Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 8, 2005
Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ń Kó sí Ìṣòro Lọ́wọ́
Ọ̀pọ̀ àgbà ọ̀jẹ̀ nínú ìwádìí ló ń sọ pé ìṣòro àwọn ọ̀dọ́ òde ìwòyí pọ̀ gàn-an ni. Ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ yìí á ṣàlàyé díẹ̀ lára ohun tó ń fà á táwọn ọ̀dọ́ fi ń kó sí pákáǹleke á sì fáwọn ọ̀dọ́ àtàwọn òbí nímọ̀ràn tó lè ràn wọ́n lọ́wọ́.
5 Wàhálà Tó Ń Báwọn Ọ̀dọ́ Òde Ìwòyí Fínra
9 Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Òde Ìwòyí Lọ́wọ́
12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
13 Àwọn Àǹfààní Tá À Ń Rí Lára Òkè
15 Mìmì Ti Ń Mi Àwọn Òkè Báyìí O
21 Ta Ló Máa Gba Àwọn Òkè Lọ́wọ́ Ewu?
25 “Ṣé Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Lè Yí Padà?”
28 Wíwo Ayé
31 Àràmàǹdà Kàlẹ́ńdà Táwọn Máyà Fi Ń Ka Ọjọ́
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Mọ Iṣẹ́ Ọwọ́ Ṣe? 22
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ka iṣẹ́ ọwọ́ sí iṣẹ́ tí kì í dùn mọ́ọ̀yàn. Ṣùgbọ́n yálà o mọ̀ tàbí o kò mọ̀, oríṣiríṣi ọ̀nà ni iṣẹ́ ọwọ́ lè gbà ṣàǹfààní fún ẹ.
Ṣé Ọlọ́run Fọwọ́ sí Kí Ọkùnrin àti Ọkùnrin Máa Fẹ́ra? 26
Ọ̀rọ̀ yìí ti fa awuyewuye tó pọ̀. Àmọ́, ìlànà tó ṣe kedere wo ni Bíbélì fúnni lórí ọ̀ràn náà?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fọ́tò tí Chris Hondros/Getty Images yà