Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

June 08, 2005

Ṣé O Máa Ń Ṣe Eré Ìmárale Tó Bó Ṣe Yẹ?

Àìṣe eré ìmárale tó bó ṣe yẹ lè mú kí àwọn àìsàn tó burú máa yọ ọ́ lẹ́nu. Kí lo lè ṣe kí ìgbòkègbodò tó ò ń fara ṣe lè máa pọ̀ sí i?

3 Ǹjẹ́ Ó Tiẹ̀ Yẹ Kó O Máa Ṣeré Ìmárale?

7 Ṣé O Máa Ń Ṣe Eré Ìmárale Tó Bó Ṣe Yẹ?

15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

18 Jẹ́ Kí Èéfín Olóró Ríbi Gbà Jáde

19 Gbogbo Wa Ló Yẹ Ká Máa Pawọ́ Pọ̀ Tún Ilé Ṣe

23 Mo Borí Ìṣòro Tíì Bá Dí Mi Lọ́wọ́ Láti Sin Ọlọ́run

28 Dídáko Sínú Ọgbà Lè Ṣe Ọ́ Láǹfààní

29 ‘Mo Fẹ́ Mọ̀ sí I Nípa Ẹ̀sìn Mi’

30 Wíwo Ayé

32 Ṣé O Rò Pé Jésù Ni Ọlọ́run?

Ṣé Bẹ́ẹ̀ Ni Ewu Pọ̀ Tó Nínú Fífẹ́ra Sọ́nà Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì? 12

Káwọn èèyàn máa fẹ́ra sọ́nà lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì ti di ohun tó wọ́pọ̀, ṣùgbọ́n ṣé ọ̀nà tí kò léwu téèyàn lè gbà wá ẹni tó máa fẹ́ ni?

Ṣó Burú Kéèyàn Máa Wá Ipò Ọlá Ni? 16

Kí ni Bíbélì sọ nípa rẹ̀?