Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 8, 2005
Ṣé Ohun Tó Ń Fa Ìbẹ̀rù Lè Tán Láyé?
Ọ̀pọ̀ nǹkan ló ń ba aráyé lẹ́rù lóde òní. Ǹjẹ́ a lè bọ́ lọ́wọ́ ohun tó ń fa ìbẹ̀rù báyìí?
4 Kí Ló Fà á Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Fi Ń Bẹ̀rù?
8 Ṣé Aráyé Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ohun Tó Ń Fa Ìbẹ̀rù?
11 Àjálù Ojoojúmọ́ Yìí Ò Wa Pọ̀ Jù?
13 Báwọn Èèyàn Ṣe Ń Dá Kún Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀
18 Láìpẹ́—Òpin Máa Dé Bá Gbogbo Àjálù
20 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
21 Oyin Ẹ̀bùn Iyebíye Fáwa Ẹ̀dá
26 Wíwo Ayé
31 Àpilẹ̀kọ Kan Tọ́jọ́ Ẹ̀ Ti Pẹ́ Wọ Àwọn Èèyàn Lọ́kàn
32 Béèyàn ṣe lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run
Ṣé Ìwòràwọ̀ Ló Máa Jẹ́ Kó O Mọ Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ?
Kí Ló Dé Tó Máa Ń Wù Mí Láti Máa Bá Ẹni Tí Kò Yẹ Rìn? 28
Ṣó ti ṣe ẹ́ rí bíi pé kó o máa bá ẹni tó o mọ̀ pé ó lè kó bá ẹ rìn? Kí ló ń mú kí irú nǹkan bẹ́ẹ̀ máa wuni?