Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 08, 2005
Ìrìn-àjò Afẹ́ Ṣé Oore Nìkan Ló Wà Nínú Ẹ̀ Ni?
Àǹfààní wo làwọn kan ti jẹ látinú ìrìn-àjò afẹ́? Síbẹ̀, àwọn ìṣòro wo ló ti dá sílẹ̀? Báwo lọ̀ràn ìrìn-àjò afẹ́ sì ṣe máa rí lọ́jọ́ iwájú?
3 “Ibi Tówó Ń Bá Wọlé Jù Lágbàáyé”
7 Bí Ọ̀ràn Ìrìn-Àjò Afẹ́ Ṣe Máa Rí Lọ́jọ́ Iwájú
10 Bí Bílíọ̀nù Kan Èèyàn á Ṣe Máa Róúnjẹ Jẹ
Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Mi Ò Fi Ní Máa Bá Àwọn Èèyàn Tí Kò Yẹ Rìn?
18 Ìjẹ́rìí Tó Fa Kíki Látẹnu Àwọn Ọ̀dọ́
26 Pankéèkì Ẹlẹ́gẹ̀ẹ́ Oúnjẹ Aládùn Ilẹ̀ Brazil
27 ‘Ó Dùn Mí Pé Mi Ò Tètè Jáwọ́’
28 Wíwo Ayé
30 ‘Ó Yẹ Kínú Ẹ Dùn sí Nǹkan Tó O Ṣe Yìí’
31 Ẹ̀rí Ọkàn Rere Ń Fògo fún Ọlọ́run
32 Ẹ Wá Gbọ́ Àsọyé Fún Gbogbo Ènìyàn
“Ta Ló Yẹ Ká Máa Ṣègbọràn Sí?”
Ẹ Wo Báwọn Èèyàn Ṣe Ta Ẹ̀jẹ̀ Sílẹ̀ Lórúkọ Kristi 12
Ìtàn kan tí ò fi bẹ́ẹ̀ tàn kálẹ̀ nínú ìtàn Mẹ́síkò jẹ́ ká rí àwọn nǹkan pàtàkì kọ́ nínú wàhálà tí Ṣọ́ọ̀ṣì bá Ìjọba fà.
Ṣó Yẹ Kó O Máa Gbàdúrà sí Màríà Wúńdíá? 20
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ èèyàn ló ń gbàdúrà sí Màríà. Ṣé irú àdúrà bẹ́ẹ̀ bá Bíbélì mu?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
© (Inventory image number: 422036) SINAFO-Fototeca Nacional