Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

October 8, 2005

Ọtí Lè Dẹkùn Múni Ǹjẹ́ O Rò Pé Ó Lè Dẹkùn Mú Ọ?

Ọtí lè dà bí ohun tó dáa kéèyàn máa fi ṣe fàájì lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan tàbí kẹ̀ kó jẹ́ àtẹ̀gùn sílé ìdààmú, àìsàn àti ikú. Báwo ló ṣe wá lè ṣe é tó ò fi ní dẹni tí àmujù ọtí dẹkùn mú?

3 Àmujù Ọtí Àkóbá Tó Ń Ṣe Fún Àwùjọ

4 Àmujù Ọtí Lè Kó Bá Ìlera Rẹ

10 Béèyàn Ṣe Lè Gba Ara Ẹ̀ Lọ́wọ́ Àmujù Ọtí

13 Gbogbo Èèyàn Ló Yẹ Kó Ní Ibùgbé

15 Kí Ló Wà Nídìí Wàhálà Àìrílégbé?

19 Bópẹ́bóyá—gbogbo Èèyàn á Nílé Gidi Lórí!

28 “Ẹ Wo Bí A Ṣe Rántí . . . Aáyù!”

30 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

31 Ó Wàásù Lọ́nà Tó Múná Dóko Nílé Ìwé

32 Ṣó o Ti Ṣe Gbogbo Nǹkan Tó Yẹ Láti Lè Wà Ńbẹ̀?

Ibi Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì—Kí Ló Wà Níbẹ̀ Tó Ṣì Yẹ Kí N Mọ̀? 23

Àwọn ọ̀dọ́ tó ń lo Íńtánẹ́ẹ̀tì ni ibi ìjíròrò orí Íńtánẹ́ẹ̀tì sábà máa ń dá lọ́rùn jù lọ. Ṣùgbọ́n, ǹjẹ́ àwọn ewu kan wà níbi ìjíròrò náà tó yẹ kó o mọ̀?

Ṣé Káwọn Obìnrin Máa Bo Ẹwà Wọn Mọ́ra Ni? 26

Àwọn ẹ̀sìn kan kì í fojú gidi wo obìnrin tó bá lo ohun ọ̀ṣọ́. Kí ni Bíbélì sọ?