Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 8, 2005
Báwo Ni Ọjọ́ Ọ̀la Ṣe Máa Rí Fáwọn Òtòṣì?
Wọ́n máa ń sọ pé ẹgbẹ́ èèyàn méjì ló wà láyé, ẹgbẹ́ ọlọ́rọ̀ àti ẹgbẹ́ òtòṣì. Báwọn òtòṣì sì ṣe ń pọ̀ sí i níye yìí, báwo ni ọjọ́ ọ̀la wọn ṣe máa rí?
3 Ayé Tí Ọrọ̀ Pín Níyà La Wà Yìí
4 Ìyàtọ̀ Tó Wà Láàárín Olówó àti Òtòṣì
11 Bí Ìwé Ìròyìn Ṣe Lágbára Tó
12 Bí Ìròyìn Ṣe Ń Dé Etígbọ̀ọ́ Aráyé
15 Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Nínú Ìwé Ìròyìn
Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Kó Sínú Ewu Níbi Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì?
28 A Rí Ọwọ́ Agbára Ọlọ́run Lára Wa
30 Àwọn Ẹlẹ́rìí Tu Ìdílé Tí Àjálù Bá Nínú
31 A Wá Ilé Míì fún Ológoṣẹ́ Tó Fara Pa
32 Ṣé Béèyàn Bá Ti Kú, Ó Kú Náà Nìyẹn?
Bó O Ṣe Lè Máa Tọ́jú Eyín Rẹ 19
Ipa wo leyín rẹ ń kó bó o bá ń rẹ́rìn-ín? Báwo lo ṣe lè fún eyín ní ìtọ́jú tó yẹ?
Ṣé Bíbélì Kọ́ni Pé Àwọn Ọkùnrin Sàn Ju Àwọn Obìnrin Lọ? 22
Ọ̀pọ̀ èèyàn ń sọ pé ńṣe ni ẹ̀kọ́ ìtẹríba tí Bíbélì fi kọ́ni ń rẹ àwọn obìnrin sílẹ̀. Ṣóòótọ́ ni?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Àwòrán ẹ̀yìn ìwé: © Fọ́tò tí Karen Robinson/Panos yà