Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

December 8, 2005

Ǹjẹ́ Ìṣòro Àìrílégbé Máa Dópin Láé?

Kí ló fà á táwọn tí ò rílé gbé fi ń pọ̀ sí i? Ọ̀nà wo ló dáa jù lọ tá a lè gbà ran àwọn tí ò rílé gbé lọ́wọ́? Ǹjẹ́ ìrètí tó ṣeé gbára lé kankan tiẹ̀ wà pé ọ̀ràn àìrílégbé á lójú lọ́jọ́ kan?

3 Àìrílégbé Ti Di Ìṣòro Tó Kárí Ayé

4 Kí Ló Ń Fa Ìṣòro Àìrílégbé?

8 Àìrílégbé​—Kí Lọ̀nà Àbáyọ?

11 Bí Oúnjẹ Bá Lọ Tán Pẹ́nrẹ́n

12 Wàhálà Tó Wà Nínú Kíkó Oúnjẹ Wọnú Ìlú Ńláńlá

19 Ǹjẹ́ Ebi Lè Tán Láyé?

20 Ǹjẹ́ O Mọ̀?

26 Ṣé Béèyàn Bá Ṣe Láǹfààní Láti Yàn Tó Ni Ìtẹ́lọ́rùn Á Ṣe Jìnnà Sí I Tó?

27 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . .

Ṣé Dandan Ni Ká Ṣègbéyàwó Níṣulọ́kà?

30 “Káàbọ̀ Sínú Ètò Jèhófà”

31 Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹrìndínláàádọ́rùn-ún Ti jí!

32 Ó Rán An Létí Àwọn Nǹkan Tó Nífẹ̀ẹ́ Sí

Mo Jẹ́ Aláàbọ̀ Ara, Síbẹ̀ Mi Ò Juwọ́ Sílẹ̀ 21

Kà nípa àgbàyanu ìgbàgbọ́ àti ìfaradà ọ̀dọ́mọkùnrin kan tó ń kojú àìlera líle koko nílẹ̀ ìbílẹ̀ rẹ̀ tí iná ogun ti ń jó.

Ṣé Ọlọ́run Ṣojúure Sáwọn Orílẹ̀-Èdè Kan Ju Àwọn Míì Lọ Ni? 24

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà gbọ́ pé Ọlọ́run ṣojúure sáwọn orílẹ̀-èdè kan ju àwọn míì lọ, àmọ́ ṣé Bíbélì fara mọ́ irú ìgbàgbọ́ bẹ́ẹ̀?