Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹrìndínláàádọ́rùn-ún Ti Jí!

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹrìndínláàádọ́rùn-ún Ti Jí!

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹrìndínláàádọ́rùn-ún Ti Jí!

ÀJỌṢE Ẹ̀DÁ

Àwọn Abiyamọ Gẹ́gẹ́ bí Olùkọ́, 3/8

Àwọn Dókítà, 2/8

Àwọn Ọ̀dọ́ Nílò Alábàárò, 11/8

Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ń Kó sí Ìṣòro Lọ́wọ́, 4/8

Ẹwà Tó Ṣe Pàtàkì Jù, 1/8

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

Àpéjọ Àgbègbè “Ìgbọràn sí Ọlọ́run,” 9/8, 10/8

Àpilẹ̀kọ Kan Tọ́jọ́ Ẹ̀ Ti Pẹ́ Wọ Àwọn Èèyàn Lọ́kàn, 8/8

A Rí Ọwọ́ Agbára Ọlọ́run Lára Wa (gbọ́mọgbọ́mọ), 11/8

Àwọn Ẹlẹ́rìí Tu Ìdílé Tí Àjálù Bá Nínú (ilẹ̀ Sípéènì), 11/8

Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Yí Padà, 4/8

Bí Wọ́n Ṣe Borí Jìnnìjìnnì Nígbà Táwọn Apániláyà Yin Bọ́ǹbù (orílẹ̀-èdè Sípéènì), 2/8

Ẹlẹ́wọ̀n Ni Wọ́n, Síbẹ̀ Wọ́n Lómìnira (ibi tí wọ́n ń kó àwọn ọ̀daràn sí nílẹ̀ Mẹ́síkò), 3/8

Ẹ̀rí Ọkàn Rere Ń Fògo fún Ọlọ́run, 9/8

Ìjẹ́rìí Tó Fa Kíki Látẹnu Àwọn Ọ̀dọ́, 9/8

“Ká Láwọn Ọ̀dọ́ Mọ̀ Pé Bọ́rọ̀ Ṣe Rí Nìyẹn Ni!” (orílẹ̀-èdè Dominican Republic), 3/8

“Káàbọ̀ Sínú Ètò Jèhófà” (orílẹ̀-èdè Finland), 12/8

‘Mo Fẹ́ Mọ̀ sí I Nípa Ẹ̀sìn Mi,’ 6/8

Ó Rán An Létí Àwọn Nǹkan Tó Nífẹ̀ẹ́ Sí (ìwé Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà), 12/8

Ó Wàásù Lọ́nà Tó Múná Dóko Nílé Ìwé (orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò), 10/8

‘Ó Yẹ Kínú Ẹ Dùn sí Nǹkan Tó O Ṣe Yìí,’ 9/8

ÀWỌN OHUN TÓ Ń ṢẸLẸ̀ NÍNÚ AYÉ

Àìrílégbé, 12/8

Àjálù, 8/8

Báwo Ni Ọjọ́ Ọ̀la Ṣe Máa Rí Fáwọn Òtòṣì? 11/8

Bíba Ilé Ayé Jẹ́, 1/8

Bí Bílíọ̀nù Kan Èèyàn Á Ṣe Máa Róúnjẹ Jẹ, 9/8

Bí Ìwé Ìròyìn Ṣe Lágbára Tó, 11/8

Fíìmù, 5/8

Ìrìn-Àjò Afẹ́, 9/8

Kíkó Oúnjẹ Wọnú Ìlú Ńláńlá, 12/8

Ohun Tó Ń Fa Ìbẹ̀rù Lè Tán Láyé 8/8

Ọtí Lè Dẹkùn Múni, 10/8

Ṣíṣàfọwọ́rá, 7/8

Wàhálà Àìrílégbé, 10/8

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ

Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Máa Fàyè Gba Èrò Òdì? 3/8

Bí Àwọn Míì Bá Fọ̀rọ̀ Wọn Lọ̀ Mí, 2/8

Bíbá Ẹni Tí Kò Yẹ Rìn? 8/8, 9/8

Bó Bá Lóun Ò Lè Fẹ́ Mi Ńkọ́? 1/8

Fífẹ́ra Sọ́nà Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì 5/8, 6/8

Ibi Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì, 10/8, 11/8

Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Bí Ọ̀dọ́bìnrin Kan Bá Dẹnu Ìfẹ́ Kọ Mí? 7/8

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Mọ Iṣẹ́ Ọwọ́? 4/8

Ṣé Dandan Ni Ká Ṣègbéyàwó Níṣulọ́kà? 12/8

ÈTÒ ỌRỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́

Bó O Ṣe Lè Rí Iṣẹ́ Tí Iṣẹ́ Náà Ò sì Ní Bọ́ Lọ́wọ́ Rẹ, 7/8

ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN

Aáyù, 10/8

A Wá Ilé Míì fún Ológoṣẹ́ Tó Fara Pa, 11/8

Tòmátì, 3/8

ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN

Àmujù Ọtí, 10/8

Àníyàn, 2/8

Bí Àpárá Ṣe Lè Ran Aláìsàn Lọ́wọ́, 5/8

Bó O Ṣe Lè lóye Dókítà Rẹ, 2/8

Èéfín Olóró (fífi pàǹtírí irúgbìn dáná), 6/8

Eré Ìmárale, 6/8

Tọ́jú Eyín Rẹ, 11/8

ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN

Aáyù (orílẹ̀-èdè Dominican Republic), 10/8

“A Kì Í Sọ̀rọ̀ Àlùfààṣá” (àwọn Apache), 7/8

Aṣọ Hanbok—Aṣọ Àwọn Ará Korea, 2/8

Báwọn Èèyàn Ṣe Ta Ẹ̀jẹ̀ Sílẹ̀ Lórúkọ Kristi (orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò), 9/8

Bí Wọ́n Ṣe Ń Gbe Omi Òjò (orílẹ̀-èdè Íńdíà), 7/8

Ihò Ngorongoro (orílẹ̀-èdè Tanzania), 1/8

Kàlẹ́ńdà Táwọn Máyà Fi Ń Ka Ọjọ́, 4/8

Nairobi“Odò Omi Tútù” (Kẹ́ńyà), 1/8

Pankéèkì Ẹlẹ́gẹ̀ẹ́—Oúnjẹ Aládùn Ilẹ̀ Brazil, 9/8

ÌSÌN

Báwọn Èèyàn Ṣe Ta Ẹ̀jẹ̀ Sílẹ̀ Lórúkọ Kristi (orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò), 9/8

Bí Ìbọ̀rìṣà Àwọn Adúláwọ̀ Ṣe Wọnú Ẹ̀sìn Kátólíìkì, 3/8

Ṣé Jésù Kristi Ni Ọlọ́run? 5/8

Ṣé Ó Yẹ Ká Máa Lo Orúkọ Ọlọ́run? 5/8

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Àwa Ti Rí Ohun Tó Sàn Jù (F. Del Rosario de Páez), 9/8

Mo Borí Ìṣòro Tíì Bá Dí Mi Lọ́wọ́ Láti Sin Ọlọ́run (I. Mikitkov), 6/8

Mo Dúpẹ́ Pé Ìrìn Mi Ò Já Sásán (C. Vavy), 3/8

Mo Jẹ́ Aláàbọ̀ Ara, Síbẹ̀ Mi Ò Juwọ́ Sílẹ̀ (K. N’Guessan), 12/8

Mo Pinnu Pé Mo Gbọ́dọ̀ Bá Ohun Tí Mò Ń Lé (M. Serna), 7/8

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ẹ Máa Wáyè Gbọ́ Tàwọn Ọmọ, 2/8

Kéèyàn Máa Lo Ère Nínú Ìjọsìn, 5/8

Kí Ọkùnrin àti Ọkùnrin Máa Fẹ́ra, 4/8

Ṣé Ọlọ́run Ṣojúure Sáwọn Orílẹ̀-Èdè Kan Ju Àwọn Míì Lọ Ni? 12/8

Ṣé Bíbélì Kọ́ni Pé Ọkùnrin Sàn Ju Obìnrin Lọ? 11/8

Ṣé Ibi Gbogbo Ni Ọlọ́run Wà? 3/8

Ṣé Ìwòràwọ̀ Ló Máa Jẹ́ Kó O Mọ Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ? 8/8

Ṣé Káwọn Obìnrin Máa Bo Ẹwà Wọn Mọ́ra Ni? 10/8

Ṣé Ọ̀dẹ̀ Lẹni Tó Bá Jẹ́ Èèyàn Pẹ̀lẹ́? 1/8

Ṣó Burú Kéèyàn Máa Wá Ipò Ọlá? 6/8

Ṣó Yẹ Kó O Máa Bẹ̀rù Amágẹ́dọ́nì? 7/8

Ṣó Yẹ Kó O Máa Gbàdúrà sí Màríà Wúńdíá? 9/8

Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN

Àwọn Òkè, 4/8

Dídáko Sínú Ọgbà Lè Ṣe Ọ́ Láǹfààní, 6/8

Iléeṣẹ́ Gbẹ̀mígbẹ̀mí (ọkọ̀ ogun tí wọ́n fi ń yin ohun ìjà olóró), 1/8

Ká Máa Pawọ́ Pọ̀ Tún Ilé Ṣe, 6/8

Ǹjẹ́ O Mọ̀? 2/8, 4/8, 6/8, 8/8, 10/8, 12/8

‘Ó Dùn Mí Pé Mi Ò Tètè Jáwọ́’ (eré ìdárayá orí fídíò), 9/8

Oyin—Ẹ̀bùn Iyebíye, 8/8

Ṣé Béèyàn Bá Ṣe Láǹfààní Láti Yàn Tó Ni Ìtẹ́lọ́rùn Á Ṣe Jìnnà Sí I Tó? 12/8

Ṣé Tẹlifóònù Alágbèéká Dára àbí Kò Dára? 3/8