JÍ! July 2009 Ìṣẹ́yún Kì í Ṣe Ọ̀nà Àbáyọ Tí Kò Léwu Ìgbà Wo Ni Ìwàláàyè Bẹ̀rẹ̀? Ìdí Tá ò Fi Ṣẹ́yún Ṣé Ọlọ́run Fẹ́ Kó O Di Ọlọ́rọ̀? Ṣó Yẹ Kó O Máa Bẹ̀rù Àwọn Òkú? Ṣó Burú Kó O Yí Ẹ̀sìn Rẹ Pa Dà? Póòpù Rọ Àwọn Ọ̀dọ́ Ẹlẹ́sìn Kátólíìkì Láti Máa Jẹ́rìí Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Kékeré Kí Ni Ìdáhùn Rẹ? Kí Nìdí Táyà Mi Fi Máa Ń Já Láti Sọ Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Fáwọn Ẹlòmíì? Kí Nìdí Táwọn Obìnrin Kì í Fi í Gba Tèmi? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Fọgbọ́n Lo Àkókò Mi?