JÍ! September 2013 | Ṣé Ìwọ́de Ló Máa Yanjú Ìṣòro Ayé?

Kà nípa ìdí tí ìwọ́de fi gbòde kan àti ibi tá a lè yíjú sí fún ìrànlọ́wọ́.

Ohun Tó Ń Lọ Láyé

Lára àwọn àkòrí náà ni: Àìsàn ibà tó ti dàwátì tẹ́lẹ̀ àmọ́ tó tún ti pa dà báyìí lórílẹ̀-èdè Gíríìsì, àwọn obìnrin tó ń bímọ láìsí nílé ọkọ lórílẹ̀-èdè Ṣáínà, àwọn ajagunfẹ̀yìntì tó ń fọwọ́ ara wọn para wọn lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́è lọ.

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bó O Ṣe Lè Bá Ọmọ Rẹ Wí

Ara ẹ̀kọ́ ní ìbáwí jẹ́. Àwọn ìlànà Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti kọ ọmọ rẹ kó lè máa gbọ́ràn kàkà kó máa ṣe agídí.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ṣé Ìwọ́de Ló Máa Yanjú Ìṣòro Ayé?

Ìwọ́de máa ń ní ipa tó lágbára gan-an. Àmọ́ ṣó lè fòpin sí ìwà àìlófin, ìnilára àti ìrẹ́jẹ?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ojú Mi Ti Rí Ìwà Ìrẹ́jẹ Tó Kọjá Àfẹnusọ

Kí nìdí tí ọ̀dọ́kùnrin kan tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè Northern Ireland fi ní ojú ìwòye tó yàtọ̀ nípa bí ìdájọ́ òdodo ṣe máa jọba láyé?

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ìjọba Ọlọ́run

Àwọn kan gbà gbọ́ pé inú ọkàn àwọn onígbàgbọ́ ni ìjọba Ọlọ́run wà tàbí pé ìsapá àwọn èèyàn ló máa mú kí ìjọba náà ṣeé ṣe. Kí ni Bíbélì sọ?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bó O Ṣe Lè Bójú Tó Ọmọ Tó Ń Ṣe Ìjọ̀ngbọ̀n

Kí lo lè ṣe tí ọmọ rẹ bá bẹ̀rẹ̀ ìjọ̀ngbọ̀n? Àwọn ìlànà Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro yìí.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ọtí Líle

Tó o bá kọ́ nípa ohun tí Bíbélì sọ, wàá lè mọ ojú tó yẹ kó o fi wo ọtí líle.

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Wẹ́rẹ́ Ni Ẹyẹ Albatross Máa Ń Fò

Wo bí ẹyẹ yìí ṣe máa ń fò fún ọ̀pọ̀ wákàtí láìmi ìyẹ́ apá rẹ̀!

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Wọ́n Bá Ń Fi Ìṣekúṣe Lọ̀ Mí?

Kà nípa bí wọ́n ṣe máa ń fi ìṣekúṣe lọni àti ohun tó o lè ṣe tí wọ́n bá ń fi ìṣekúṣe lọ̀ ẹ́.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?

Ọ̀rọ tó o fi ránṣẹ́ lórí fóònù lè ba àjọṣe tó o ní pẹ̀lú àwọn míì jẹ́, ó sì lè bà ẹ́ lórúkọ̀ jẹ́. Kà bó ṣe lè ṣẹlẹ̀.

Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Ní Àìsàn Tó Ò Ń Bá Fínra? (Apá 1)

Àwọn ọ̀dọ́ mẹ́rin sọ ohun tó ń jẹ́ kí wọ́n lè máa fara da àìsàn tó ń ṣe wọ́n, kínú wọn sì máa dùn.

Bó O Ṣe Lè Borí Ẹni Tó Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ Láì Bá A Jà

Kọ́ nípa ohun tó ń mú kí àwọn ọmọ kan máa halẹ̀ mọ́ àwọn ọmọ míì àti bí o ṣe lè borí wọn.