JÍ! July 2014

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìbálòpọ̀?

Tí wọ́n bá bi ẹ́ pé, ‘Ṣó o ti ní ìbálòpọ̀ rí?’ ṣé o lè fi Bíbélì ṣàlàyé ohun tó o gbà gbọ́ nípa ìbálòpọ̀?

Ohun Táwọn Ọ̀dọ́ Sọ Nípa Owó

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó o ṣe lè fowó pa mọ́, bó ṣe yẹ kó o ná an àti bó ò ṣe ní sọ ara rẹ di ẹrú owó.

Wọ́n Rí Mósè, Ọmọ Jòjòló

Àwọn wo ló wà nínú àwòrán náà? Ka ìtàn Bíbélì tó wà ní Ẹ́kísódù orí 2 kó o lè rí ìdáhùn.